Sáàmù 78:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Wọ́n pe Ọlọ́run níjà* nínú ọkàn wọn,+Bí wọ́n ṣe ń béèrè oúnjẹ tí ọkàn wọn fà sí.* 1 Kọ́ríńtì 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Bẹ́ẹ̀ ni kí a má ṣe dán Jèhófà* wò,+ bí àwọn kan nínú wọn ṣe dán an wò, tí ejò sì ṣán wọn pa.+