ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 10:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Àwọn eéṣú náà kún gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì, wọ́n sì bo gbogbo agbègbè Íjíbítì.+ Wọ́n ṣọṣẹ́ gan-an;+ eéṣú ò tíì pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ rí, wọn ò sì ní pọ̀ tó bẹ́ẹ̀ mọ́ láé. 15 Wọ́n bo gbogbo ilẹ̀ náà, wọ́n sì mú kí ilẹ̀ náà ṣókùnkùn. Wọ́n jẹ gbogbo ewéko ilẹ̀ náà run àti gbogbo èso igi tí òjò yìnyín ṣẹ́ kù; kò sí ewé kankan lórí àwọn igi tàbí ohun ọ̀gbìn ní gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́