-
Ẹ́kísódù 10:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Wọ́n á bo ilẹ̀ débi pé ilẹ̀ ò ní ṣeé rí. Wọ́n á jẹ ohun tó ṣẹ́ kù fún yín ní àjẹrun, èyí tí òjò yìnyín ṣẹ́ kù, wọ́n á sì jẹ gbogbo igi tó ń hù nínú oko run.+
-
-
Sáàmù 105:34, 35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ó ní kí àwọn eéṣú ya wọlé,
Àwọn ọmọ eéṣú tí kò níye.+
35 Wọ́n jẹ gbogbo ewéko ilẹ̀ náà,
Wọ́n sì jẹ irè oko wọn.
-