Sáàmù 44:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Dìde. Kí ló dé tí o ṣì fi ń sùn, Jèhófà?+ Jí! Má ṣe ta wá nù títí láé.+