Sáàmù 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Dìde nínú ìbínú rẹ, Jèhófà;Gbéra láti kojú àwọn ọ̀tá mi nínú ìbínú wọn;+Jí nítorí mi, kí o sì mú kí wọ́n ṣe ìdájọ́ òdodo.+ Sáàmù 78:65, 66 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 65 Nígbà náà, Jèhófà jí bíi pé láti ojú oorun,+Bí akíkanjú ọkùnrin+ tí wáìnì dá lójú rẹ̀ nígbà tó jí. 66 Ó lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ pa dà;+Ó mú kí ìtìjú ayérayé bá wọn.
6 Dìde nínú ìbínú rẹ, Jèhófà;Gbéra láti kojú àwọn ọ̀tá mi nínú ìbínú wọn;+Jí nítorí mi, kí o sì mú kí wọ́n ṣe ìdájọ́ òdodo.+
65 Nígbà náà, Jèhófà jí bíi pé láti ojú oorun,+Bí akíkanjú ọkùnrin+ tí wáìnì dá lójú rẹ̀ nígbà tó jí. 66 Ó lé àwọn ọ̀tá rẹ̀ pa dà;+Ó mú kí ìtìjú ayérayé bá wọn.