Sáàmù 104:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó ti gbé ayé kalẹ̀ sórí ìpìlẹ̀ rẹ̀;+A kì yóò ṣí i nípò* títí láé àti láéláé.+ Sáàmù 119:90 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 90 Òtítọ́ rẹ wà láti ìran dé ìran.+ O ti fìdí ayé múlẹ̀ gbọn-in, kó lè máa wà nìṣó.+ Oníwàásù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìran kan ń lọ, ìran kan sì ń bọ̀,Àmọ́ ayé wà* títí láé.+