-
Sáàmù 85:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ṣé títí láé ni wàá máa bínú sí wa ni?+
Ṣé wàá jẹ́ kí ìbínú rẹ máa lọ láti ìran dé ìran ni?
-
-
Àìsáyà 64:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Jọ̀ọ́, wò wá, torí èèyàn rẹ ni gbogbo wa.
-