-
Jeremáyà 51:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 ‘Kí ìwà ipá tí wọ́n hù sí mi àti sí ara mi wá sórí Bábílónì!’ ni ẹni tó ń gbé Síónì wí.+
‘Kí ẹ̀jẹ̀ mi sì wá sórí àwọn tó ń gbé Kálídíà!’ ni Jerúsálẹ́mù wí.”
-