ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 25:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Kí àwọn kérúbù náà na ìyẹ́ wọn méjèèjì sókè, kí wọ́n fi bo ìbòrí náà,+ kí wọ́n sì dojú kọra. Kí àwọn kérúbù náà sì máa wo ìbòrí náà.

  • Ẹ́kísódù 25:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Màá pàdé rẹ níbẹ̀, màá sì bá ọ sọ̀rọ̀ látorí ìbòrí náà.+ Láti àárín àwọn kérúbù méjì tó wà lórí àpótí Ẹ̀rí náà ni màá ti jẹ́ kí o mọ gbogbo ohun tí màá pa láṣẹ fún ọ pé kí o sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

  • 1 Sámúẹ́lì 4:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nítorí náà, wọ́n rán àwọn èèyàn lọ sí Ṣílò, láti ibẹ̀, wọ́n gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ẹni tó ń jókòó lórí* àwọn kérúbù.+ Àwọn ọmọkùnrin Élì méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì+ sì wà níbẹ̀ pẹ̀lú àpótí májẹ̀mú Ọlọ́run tòótọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́