ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 25:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Kí o fi wúrà ṣe kérúbù méjì; kó jẹ́ iṣẹ́ ọnà tí o fi òòlù ṣe sí ìkángun méjèèjì ìbòrí náà.+

  • Nọ́ńbà 7:89
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 89 Nígbàkigbà tí Mósè bá lọ sínú àgọ́ ìpàdé láti bá Ọlọ́run*+ sọ̀rọ̀, ó máa ń gbọ́ ohùn tó ń bá a sọ̀rọ̀ láti òkè ìbòrí+ àpótí Ẹ̀rí, láàárín àwọn kérúbù+ méjèèjì; Ọlọ́run á sì bá a sọ̀rọ̀.

  • 2 Àwọn Ọba 19:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Hẹsikáyà wá bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà+ níwájú Jèhófà, ó sọ pé: “Ìwọ Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, tí o jókòó sórí ìtẹ́ lókè* àwọn kérúbù,+ ìwọ nìkan ni Ọlọ́run tòótọ́ lórí gbogbo ìjọba ayé.+ Ìwọ lo dá ọ̀run àti ayé.

  • Sáàmù 80:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 80 Fetí sílẹ̀, ìwọ Olùṣọ́ Àgùntàn Ísírẹ́lì,

      Ìwọ tí ò ń darí Jósẹ́fù bí agbo ẹran.+

      Ìwọ tí ò ń jókòó lórí* àwọn kérúbù,+

      Máa tàn yanran.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́