ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 25:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Kí o fi wúrà ṣe kérúbù méjì; kó jẹ́ iṣẹ́ ọnà tí o fi òòlù ṣe sí ìkángun méjèèjì ìbòrí náà.+

  • 1 Sámúẹ́lì 4:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Nítorí náà, wọ́n rán àwọn èèyàn lọ sí Ṣílò, láti ibẹ̀, wọ́n gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ẹni tó ń jókòó lórí* àwọn kérúbù.+ Àwọn ọmọkùnrin Élì méjèèjì, Hófínì àti Fíníhásì+ sì wà níbẹ̀ pẹ̀lú àpótí májẹ̀mú Ọlọ́run tòótọ́.

  • Sáàmù 80:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 80 Fetí sílẹ̀, ìwọ Olùṣọ́ Àgùntàn Ísírẹ́lì,

      Ìwọ tí ò ń darí Jósẹ́fù bí agbo ẹran.+

      Ìwọ tí ò ń jókòó lórí* àwọn kérúbù,+

      Máa tàn yanran.*

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́