-
Sáàmù 85:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ṣé títí láé ni wàá máa bínú sí wa ni?+
Ṣé wàá jẹ́ kí ìbínú rẹ máa lọ láti ìran dé ìran ni?
-
-
Ìdárò 3:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 O ti fi àwọsánmà dí ọ̀nà tó lọ sọ́dọ̀ rẹ, kí àdúrà wa má bàa kọjá.+
-