Àìsáyà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí pé ilé Ísírẹ́lì ni ọgbà àjàrà Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;+Àwọn èèyàn Júdà sì ni oko* tó fẹ́ràn. Ó ń retí ìdájọ́ òdodo,+Àmọ́ wò ó! ìrẹ́jẹ ló wà;Ó ń retí òdodo,Àmọ́ wò ó! igbe ìdààmú ló wà.”+
7 Torí pé ilé Ísírẹ́lì ni ọgbà àjàrà Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;+Àwọn èèyàn Júdà sì ni oko* tó fẹ́ràn. Ó ń retí ìdájọ́ òdodo,+Àmọ́ wò ó! ìrẹ́jẹ ló wà;Ó ń retí òdodo,Àmọ́ wò ó! igbe ìdààmú ló wà.”+