Sáàmù 80:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 O mú kí àjàrà+ kan kúrò ní Íjíbítì. O lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde, o sì gbin àjàrà náà.+ Jeremáyà 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọ̀pọ̀ olùṣọ́ àgùntàn ti ba ọgbà àjàrà mi jẹ́;+Wọ́n ti tẹ oko mi mọ́lẹ̀.+ Wọ́n ti sọ oko mi tó dára di aginjù.
10 Ọ̀pọ̀ olùṣọ́ àgùntàn ti ba ọgbà àjàrà mi jẹ́;+Wọ́n ti tẹ oko mi mọ́lẹ̀.+ Wọ́n ti sọ oko mi tó dára di aginjù.