Àìsáyà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Torí pé ilé Ísírẹ́lì ni ọgbà àjàrà Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;+Àwọn èèyàn Júdà sì ni oko* tó fẹ́ràn. Ó ń retí ìdájọ́ òdodo,+Àmọ́ wò ó! ìrẹ́jẹ ló wà;Ó ń retí òdodo,Àmọ́ wò ó! igbe ìdààmú ló wà.”+ Jeremáyà 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Mo gbìn ọ́ bí àjàrà pupa tó dára,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ èso tí kò lábùkù;Báwo lo ṣe wá di ọ̀mùnú àjàrà ilẹ̀ òkèèrè tí kò dára lójú mi?’+
7 Torí pé ilé Ísírẹ́lì ni ọgbà àjàrà Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun;+Àwọn èèyàn Júdà sì ni oko* tó fẹ́ràn. Ó ń retí ìdájọ́ òdodo,+Àmọ́ wò ó! ìrẹ́jẹ ló wà;Ó ń retí òdodo,Àmọ́ wò ó! igbe ìdààmú ló wà.”+
21 Mo gbìn ọ́ bí àjàrà pupa tó dára,+ gbogbo rẹ̀ jẹ́ èso tí kò lábùkù;Báwo lo ṣe wá di ọ̀mùnú àjàrà ilẹ̀ òkèèrè tí kò dára lójú mi?’+