Jóòbù 36:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kì í gbé ojú rẹ̀ kúrò lára àwọn olódodo;+Ó ń fi wọ́n sórí ìtẹ́ pẹ̀lú àwọn ọba,*+ ó sì gbé wọn ga títí láé. Sáàmù 34:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ojú Jèhófà wà lára àwọn olódodo,+Etí rẹ̀ sì ṣí sí igbe wọn fún ìrànlọ́wọ́.+ 1 Pétérù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+
7 Kì í gbé ojú rẹ̀ kúrò lára àwọn olódodo;+Ó ń fi wọ́n sórí ìtẹ́ pẹ̀lú àwọn ọba,*+ ó sì gbé wọn ga títí láé.
12 Nítorí ojú Jèhófà* wà lára àwọn olódodo, etí rẹ̀ sì ṣí sí ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ wọn;+ àmọ́ Jèhófà* kọjú ìjà sí àwọn tó ń ṣe ohun búburú.”+