ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 15:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ọ̀tá sọ pé: ‘Màá lépa wọn! Màá lé wọn bá!

      Màá pín ẹrù ogun wọn títí yóò fi tẹ́ mi* lọ́rùn!

      Màá fa idà mi yọ! Ọwọ́ mi yóò ṣẹ́gun wọn!’+

       10 O fẹ́ èémí rẹ jáde, òkun sì bò wọ́n;+

      Wọ́n rì sínú alagbalúgbú omi bí òjé.

  • 1 Sámúẹ́lì 2:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ẹ má ṣe máa fọ́nnu;

      Ẹ má ṣe jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ìgbéraga ti ẹnu yín jáde,

      Nítorí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run ìmọ̀,+

      Òun sì ni ó ń ṣàyẹ̀wò nǹkan lọ́nà tó tọ́.

  • Ìsíkíẹ́lì 28:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Ọmọ èèyàn, sọ fún aṣáájú Tírè pé, ‘Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí:

      “Torí pé ò ń gbéra ga nínú ọkàn rẹ,+ tí o sì ń sọ pé, ‘ọlọ́run ni mí.

      Orí ìtẹ́ ọlọ́run ni mo jókòó sí láàárín òkun.’+

      Àmọ́ èèyàn lásán ni ọ́, o kì í ṣe ọlọ́run,

      Bí o tiẹ̀ ń pe ara rẹ ní ọlọ́run nínú ọkàn rẹ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́