Sáàmù 146:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé àwọn olórí*Tàbí lé ọmọ èèyàn, tí kò lè gbani là.+ 4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+
3 Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé àwọn olórí*Tàbí lé ọmọ èèyàn, tí kò lè gbani là.+ 4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+