ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 62:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Èémí lásán ni àwọn ọmọ èèyàn,

      Ẹ̀tàn ni àwọn ọmọ aráyé.+

      Tí a bá gbé gbogbo wọn lórí òṣùwọ̀n, wọ́n fúyẹ́ ju èémí lásán.+

  • Sáàmù 118:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ó sàn láti fi Jèhófà ṣe ibi ààbò

      Ju láti gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn.+

       9 Ó sàn láti fi Jèhófà ṣe ibi ààbò

      Ju láti gbẹ́kẹ̀ lé àwọn olórí.+

  • Àìsáyà 2:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Fún àǹfààní ara yín, ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn lásán mọ́,

      Ẹni tí kò yàtọ̀ sí èémí ihò imú rẹ̀.*

      Kí nìdí tí ẹ fi máa kà á sí?

  • Jeremáyà 17:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

      “Ègún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn lásánlàsàn,+

      Tó gbára lé agbára èèyàn,*+

      Tí ọkàn rẹ̀ sì pa dà lẹ́yìn Jèhófà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́