Sáàmù 40:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Aláyọ̀ ni ọkùnrin tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà,Tí kò sì yíjú sí àwọn aláfojúdi tàbí àwọn ẹlẹ́tàn.* Sáàmù 146:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé àwọn olórí*Tàbí lé ọmọ èèyàn, tí kò lè gbani là.+ 4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+ Jeremáyà 17:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ègún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn lásánlàsàn,+Tó gbára lé agbára èèyàn,*+Tí ọkàn rẹ̀ sì pa dà lẹ́yìn Jèhófà.
3 Ẹ má ṣe gbẹ́kẹ̀ lé àwọn olórí*Tàbí lé ọmọ èèyàn, tí kò lè gbani là.+ 4 Ẹ̀mí* rẹ̀ jáde lọ, ó pa dà sínú ilẹ̀;+Ọjọ́ yẹn gan-an ni èrò inú rẹ̀ ṣègbé.+
5 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ègún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé èèyàn lásánlàsàn,+Tó gbára lé agbára èèyàn,*+Tí ọkàn rẹ̀ sì pa dà lẹ́yìn Jèhófà.