Émọ́sì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Tírè+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí wọ́n kó gbogbo àwọn tí wọ́n mú nígbèkùn, wọ́n sì fà wọ́n lé Édómù lọ́wọ́,Àti nítorí pé wọn kò rántí májẹ̀mú àwọn arákùnrin.+
9 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,‘Nítorí ìdìtẹ̀ mẹ́ta Tírè+ àti nítorí mẹ́rin, mi ò ní yí ọwọ́ mi pa dà,Nítorí wọ́n kó gbogbo àwọn tí wọ́n mú nígbèkùn, wọ́n sì fà wọ́n lé Édómù lọ́wọ́,Àti nítorí pé wọn kò rántí májẹ̀mú àwọn arákùnrin.+