ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 26:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Jèhófà, mo nífẹ̀ẹ́ ilé tí ò ń gbé,+

      Ibi tí ògo rẹ wà.+

  • Sáàmù 27:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ohun kan ni mo béèrè lọ́wọ́ Jèhófà,

      Òun ni mo sì ń wá, pé:

      Kí n máa gbé inú ilé Jèhófà ní gbogbo ọjọ́ ayé mi,+

      Kí n máa rí adùn Jèhófà,

      Kí n sì máa fi ìmọrírì* wo tẹ́ńpìlì* rẹ̀.+

  • Sáàmù 43:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Rán ìmọ́lẹ̀ rẹ àti òtítọ́ rẹ jáde.+

      Kí wọ́n máa darí mi;+

      Kí wọ́n ṣamọ̀nà mi sí òkè mímọ́ rẹ àti sí àgọ́ ìjọsìn rẹ títóbi.+

       4 Nígbà náà, màá wá síbi pẹpẹ Ọlọ́run,+

      Sọ́dọ̀ Ọlọ́run, tí ó jẹ́ ayọ̀ ńlá mi.

      Màá sì fi háàpù yìn ọ́,+ ìwọ Ọlọ́run, Ọlọ́run mi.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́