1 Kíróníkà 16:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Torí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wọlé, wọ́n sì gbé e kalẹ̀ sí àyè rẹ̀ nínú àgọ́ tí Dáfídì pa fún un;+ wọ́n mú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ wá síwájú Ọlọ́run tòótọ́.+ Sáàmù 78:68, 69 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 68 Àmọ́, ó yan ẹ̀yà Júdà,+Òkè Síónì, èyí tí ó nífẹ̀ẹ́.+ 69 Ó mú kí ibi mímọ́ rẹ̀ lè máa wà títí lọ bí ọ̀run,*+Bí ayé tí ó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ títí láé.+
16 Torí náà, wọ́n gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wọlé, wọ́n sì gbé e kalẹ̀ sí àyè rẹ̀ nínú àgọ́ tí Dáfídì pa fún un;+ wọ́n mú àwọn ẹbọ sísun àti àwọn ẹbọ ìrẹ́pọ̀ wá síwájú Ọlọ́run tòótọ́.+
68 Àmọ́, ó yan ẹ̀yà Júdà,+Òkè Síónì, èyí tí ó nífẹ̀ẹ́.+ 69 Ó mú kí ibi mímọ́ rẹ̀ lè máa wà títí lọ bí ọ̀run,*+Bí ayé tí ó fìdí rẹ̀ múlẹ̀ títí láé.+