Sáàmù 103:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Kì í fìgbà gbogbo wá àṣìṣe,+Kì í sì í bínú títí lọ.+ Àìsáyà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní ọjọ́ yẹn, ó dájú pé o máa sọ pé: “Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà,Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé o bínú sí mi,Ìbínú rẹ ti wá rọlẹ̀, o sì tù mí nínú.+
12 Ní ọjọ́ yẹn, ó dájú pé o máa sọ pé: “Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà,Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé o bínú sí mi,Ìbínú rẹ ti wá rọlẹ̀, o sì tù mí nínú.+