Sáàmù 25:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọlọ́run mi, ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀ lé;+Má ṣe jẹ́ kí ojú tì mí.+ Má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi yọ̀ mí.+ Sáàmù 35:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Má ṣe jẹ́ kí àwọn tó sọ ara wọn di ọ̀tá mi láìnídìí yọ̀ mí;Má ṣe jẹ́ kí àwọn tó kórìíra mi láìnídìí+ wò mí tìkà-tẹ̀gbin.+
19 Má ṣe jẹ́ kí àwọn tó sọ ara wọn di ọ̀tá mi láìnídìí yọ̀ mí;Má ṣe jẹ́ kí àwọn tó kórìíra mi láìnídìí+ wò mí tìkà-tẹ̀gbin.+