Àìsáyà 26:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 O máa dáàbò bo àwọn tó gbára lé ọ pátápátá;*O máa fún wọn ní àlàáfíà tí kò lópin, +Torí pé ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé.+
3 O máa dáàbò bo àwọn tó gbára lé ọ pátápátá;*O máa fún wọn ní àlàáfíà tí kò lópin, +Torí pé ìwọ ni wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé.+