ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 2:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́,*

      Òkè ilé Jèhófà

      Máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in sórí àwọn òkè,+

      A sì máa gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,

      Gbogbo orílẹ̀-èdè á sì máa rọ́ lọ síbẹ̀.+

       3 Ọ̀pọ̀ èèyàn máa lọ, wọ́n á sì sọ pé:

      “Ẹ wá, ẹ jẹ́ ká lọ sórí òkè Jèhófà,

      Sí ilé Ọlọ́run Jékọ́bù.+

      Ó máa kọ́ wa ní àwọn ọ̀nà rẹ̀,

      A ó sì máa rìn ní àwọn ọ̀nà rẹ̀.”+

      Torí òfin* máa jáde láti Síónì,

      Ọ̀rọ̀ Jèhófà sì máa jáde láti Jerúsálẹ́mù.+

  • Sekaráyà 14:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Jèhófà yóò sì jẹ́ Ọba lórí gbogbo ayé.+ Jèhófà yóò jẹ́ ọ̀kan ní ọjọ́ yẹn,+ orúkọ rẹ̀ yóò sì jẹ́ ọ̀kan.+

  • Ìfihàn 7:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Lẹ́yìn èyí, wò ó! mo rí ogunlọ́gọ̀ èèyàn,* tí èèyàn kankan kò lè ka iye wọn, wọ́n wá látinú gbogbo orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà àti èèyàn àti ahọ́n,*+ wọ́n dúró níwájú ìtẹ́ àti níwájú Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà, wọ́n wọ aṣọ funfun;+ imọ̀ ọ̀pẹ sì wà lọ́wọ́ wọn.+ 10 Wọ́n ń ké jáde pé: “Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wa tó jókòó sórí ìtẹ́+ àti Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà ni ìgbàlà wa ti wá.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́