Àìsáyà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́,*Òkè ilé Jèhófà Máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in sórí àwọn òkè,+A sì máa gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,Gbogbo orílẹ̀-èdè á sì máa rọ́ lọ síbẹ̀.+ Ìfihàn 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ Jèhófà,* tí kò ní yin orúkọ rẹ lógo, torí pé ìwọ nìkan ni adúróṣinṣin?+ Torí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè máa wá jọ́sìn níwájú rẹ,+ torí a ti fi àwọn àṣẹ òdodo rẹ hàn kedere.”
2 Ní apá ìgbẹ̀yìn àwọn ọjọ́,*Òkè ilé Jèhófà Máa fìdí múlẹ̀ gbọn-in sórí àwọn òkè,+A sì máa gbé e ga ju àwọn òkè kéékèèké lọ,Gbogbo orílẹ̀-èdè á sì máa rọ́ lọ síbẹ̀.+
4 Ta ni kò ní bẹ̀rù rẹ Jèhófà,* tí kò ní yin orúkọ rẹ lógo, torí pé ìwọ nìkan ni adúróṣinṣin?+ Torí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè máa wá jọ́sìn níwájú rẹ,+ torí a ti fi àwọn àṣẹ òdodo rẹ hàn kedere.”