ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 27:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Jèhófà, kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ,+

      Darí mi ní ọ̀nà ìdúróṣinṣin nítorí àwọn ọ̀tá mi.

  • Sáàmù 119:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Jèhófà,+ kọ́ mi kí n lè máa tè lé àwọn ìlànà rẹ,

      Màá sì tẹ̀ lé e délẹ̀délẹ̀.+

  • Sáàmù 143:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ní àárọ̀, jẹ́ kí n gbọ́ nípa ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀,

      Nítorí mo gbẹ́kẹ̀ lé ọ.

      Jẹ́ kí n mọ ọ̀nà tó yẹ kí n máa rìn,+

      Nítorí ìwọ ni mo yíjú sí.*

  • Àìsáyà 54:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Jèhófà máa kọ́ gbogbo àwọn ọmọ* rẹ,+

      Àlàáfíà àwọn ọmọ* rẹ sì máa pọ̀ gan-an.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́