Sáàmù 150:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ fi ìlù tanboríìnì+ àti ijó àjóyípo yìn ín. Ẹ fi àwọn nǹkan olókùn tín-ín-rín+ àti fèrè*+ yìn ín.
4 Ẹ fi ìlù tanboríìnì+ àti ijó àjóyípo yìn ín. Ẹ fi àwọn nǹkan olókùn tín-ín-rín+ àti fèrè*+ yìn ín.