-
Sáàmù 92:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
92 Ó dára láti máa fi ọpẹ́ fún Jèhófà+
Àti láti máa fi orin yin* orúkọ rẹ, ìwọ Ẹni Gíga Jù Lọ,
-
Sáàmù 92:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Pẹ̀lú ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín mẹ́wàá àti gòjé,
Nípasẹ̀ háàpù tó ń dún dáadáa.+
-
-
-