-
Sáàmù 33:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ẹ kọ orin tuntun sí i;+
Ẹ fi ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín dárà, bí ẹ ti ń kígbe ayọ̀.
-
-
Sáàmù 40:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ó wá fi orin tuntun sí mi lẹ́nu,+
Ìyìn sí Ọlọ́run wa.
Ọ̀pọ̀ èèyàn á rí nǹkan yìí, ẹ̀rù Ọlọ́run á bà wọ́n,
Wọ́n á sì gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà.
-