Ìfihàn 7:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo sì gbọ́ iye àwọn tí a gbé èdìdì lé, ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì+ (144,000), a gbé èdìdì lé wọn látinú gbogbo ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì:+
4 Mo sì gbọ́ iye àwọn tí a gbé èdìdì lé, ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì+ (144,000), a gbé èdìdì lé wọn látinú gbogbo ẹ̀yà àwọn ọmọ Ísírẹ́lì:+