-
Róòmù 9:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Àmọ́, kì í ṣe pé ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ti kùnà. Torí kì í ṣe gbogbo àwọn tó wá látinú Ísírẹ́lì ni “Ísírẹ́lì” lóòótọ́.+
-
-
Ìfihàn 21:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ó ní ògiri ńlá tó ga fíofío, ó sì ní ẹnubodè méjìlá (12), àwọn áńgẹ́lì méjìlá (12) wà ní àwọn ẹnubodè náà, a sì kọ orúkọ àwọn ẹ̀yà méjìlá (12) àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí àwọn ẹnubodè náà.
-