Róòmù 2:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nítorí ẹni tó jẹ́ Júù ní òde kì í ṣe Júù,+ bẹ́ẹ̀ ni ìdádọ̀dọ́* kì í ṣe ohun tó wà ní òde ara.+ Ìfihàn 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 ‘Mo mọ ìpọ́njú àti ipò òṣì rẹ—àmọ́ ọlọ́rọ̀ ni ọ́+—àti ọ̀rọ̀ òdì àwọn tó ń pe ara wọn ní Júù, síbẹ̀ tí wọn kì í ṣe Júù, àmọ́ sínágọ́gù Sátánì ni wọ́n.+
9 ‘Mo mọ ìpọ́njú àti ipò òṣì rẹ—àmọ́ ọlọ́rọ̀ ni ọ́+—àti ọ̀rọ̀ òdì àwọn tó ń pe ara wọn ní Júù, síbẹ̀ tí wọn kì í ṣe Júù, àmọ́ sínágọ́gù Sátánì ni wọ́n.+