Ìfihàn 14:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn yìí kò fi obìnrin sọ ara wọn di aláìmọ́; kódà, wúńdíá ni wọ́n.+ Àwọn ló ń tẹ̀ lé Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà lọ síbikíbi tó bá ń lọ.+ A rà wọ́n+ látinú aráyé, wọ́n sì jẹ́ àkọ́so+ fún Ọlọ́run àti fún Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà,
4 Àwọn yìí kò fi obìnrin sọ ara wọn di aláìmọ́; kódà, wúńdíá ni wọ́n.+ Àwọn ló ń tẹ̀ lé Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà lọ síbikíbi tó bá ń lọ.+ A rà wọ́n+ látinú aráyé, wọ́n sì jẹ́ àkọ́so+ fún Ọlọ́run àti fún Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà,