Sáàmù 27:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi.+ Má fi ìbínú lé ìránṣẹ́ rẹ kúrò. Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi;+Má pa mí tì, má sì fi mí sílẹ̀, Ọlọ́run ìgbàlà mi. Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+
9 Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi.+ Má fi ìbínú lé ìránṣẹ́ rẹ kúrò. Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi;+Má pa mí tì, má sì fi mí sílẹ̀, Ọlọ́run ìgbàlà mi.
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+