-
Jóòbù 17:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ìrora ti sọ ojú mi di bàìbàì,+
Òjìji sì ni gbogbo apá àti ẹsẹ̀ mi.
-
-
Ìdárò 3:49Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
49 Omijé ń dà lójú mi pẹ̀rẹ̀pẹ̀rẹ̀, kò dáwọ́ dúró,+
-