Sáàmù 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ọ̀pọ̀ ń sọ nípa mi* pé: “Ọlọ́run ò ní gbà á sílẹ̀.”+ (Sélà)* Sáàmù 42:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín nítorí ìkórìíra tó lágbára tí wọ́n ní sí mi;*Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+ Sáàmù 79:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí nìdí tí àwọn orílẹ̀-èdè á fi sọ pé: “Ọlọ́run wọn dà?”+ Níṣojú wa, jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè mọ̀ péO ti gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí wọ́n ta sílẹ̀.+
2 Ọ̀pọ̀ ń sọ nípa mi* pé: “Ọlọ́run ò ní gbà á sílẹ̀.”+ (Sélà)* Sáàmù 42:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín nítorí ìkórìíra tó lágbára tí wọ́n ní sí mi;*Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+ Sáàmù 79:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Kí nìdí tí àwọn orílẹ̀-èdè á fi sọ pé: “Ọlọ́run wọn dà?”+ Níṣojú wa, jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè mọ̀ péO ti gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí wọ́n ta sílẹ̀.+
10 Àwọn ọ̀tá mi ń fi mí ṣẹ̀sín nítorí ìkórìíra tó lágbára tí wọ́n ní sí mi;*Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, wọ́n ń fi mí ṣẹ̀sín, wọ́n ń sọ pé: “Ọlọ́run rẹ dà?”+
10 Kí nìdí tí àwọn orílẹ̀-èdè á fi sọ pé: “Ọlọ́run wọn dà?”+ Níṣojú wa, jẹ́ kí àwọn orílẹ̀-èdè mọ̀ péO ti gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí wọ́n ta sílẹ̀.+