Sáàmù 55:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní alẹ́, ní òwúrọ̀ àti ní ọ̀sán, ìdààmú bá mi, mò ń kérora,*+Ó sì ń gbọ́ ohùn mi.+