Sáàmù 40:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wo bí àwọn ohun tí o ṣe ti pọ̀ tó,Jèhófà Ọlọ́run mi,Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ àti èrò rẹ sí wa.+ Kò sí ẹni tí a lè fi ọ́ wé;+Tí mo bá ní kí n máa wí, kí n sì máa sọ nípa wọn,Wọ́n pọ̀ ju ohun tí mo lè ròyìn!+ Sáàmù 71:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọlọ́run, òdodo rẹ ga dé òkè;+O ti ṣe àwọn ohun ńlá;Ọlọ́run, ta ló dà bí rẹ?+
5 Wo bí àwọn ohun tí o ṣe ti pọ̀ tó,Jèhófà Ọlọ́run mi,Àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ àti èrò rẹ sí wa.+ Kò sí ẹni tí a lè fi ọ́ wé;+Tí mo bá ní kí n máa wí, kí n sì máa sọ nípa wọn,Wọ́n pọ̀ ju ohun tí mo lè ròyìn!+