Ẹ́kísódù 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+ Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà, Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+
16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+ Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà, Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+