-
2 Sámúẹ́lì 7:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Orílẹ̀-èdè wo ní gbogbo ayé ló dà bí àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì?+ Ọlọ́run lọ rà wọ́n pa dà nítorí wọ́n jẹ́ èèyàn rẹ̀,+ ó sì ṣe orúkọ fún ara rẹ̀+ bí ó ṣe ń ṣe àwọn ohun ńlá àti àwọn ohun àgbàyanu fún wọn.+ O lé àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn ọlọ́run wọn jáde nítorí àwọn èèyàn rẹ, tí o rà pa dà fún ara rẹ láti Íjíbítì.
-
-
Àìsáyà 43:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
“Má bẹ̀rù, torí mo ti tún ọ rà.+
Mo ti fi orúkọ rẹ pè ọ́.
Tèmi ni ọ́.
-