Àìsáyà 44:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan! Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀! Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín! Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+ Jeremáyà 50:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àmọ́, Olùtúnrà wọn lágbára.+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+ Ó dájú pé á gba ẹjọ́ wọn rò,+Kí ó lè fún ilẹ̀ náà ní ìsinmi+Kí ó sì mú rúkèrúdò bá àwọn tó ń gbé ní Bábílónì.”+
23 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run,Torí Jèhófà ti ṣe nǹkan kan! Ẹ kígbe ìṣẹ́gun, ẹ̀yin ibi tó jìn ní ilẹ̀! Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin òkè,+Ẹ̀yin igbó àti gbogbo igi yín! Torí Jèhófà ti tún Jékọ́bù rà,Ó sì ń fi ẹwà rẹ̀ hàn lára Ísírẹ́lì.”+
34 Àmọ́, Olùtúnrà wọn lágbára.+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀.+ Ó dájú pé á gba ẹjọ́ wọn rò,+Kí ó lè fún ilẹ̀ náà ní ìsinmi+Kí ó sì mú rúkèrúdò bá àwọn tó ń gbé ní Bábílónì.”+