Àìsáyà 49:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+ Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+ Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+ Àìsáyà 55:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ máa fi ayọ̀ jáde lọ,+A sì máa mú yín pa dà ní àlàáfíà.+ Àwọn òkè ńlá àtàwọn òkè kéékèèké máa fi igbe ayọ̀ túra ká níwájú yín,+Gbogbo àwọn igi inú igbó sì máa pàtẹ́wọ́.+
13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+ Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+ Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+
12 Ẹ máa fi ayọ̀ jáde lọ,+A sì máa mú yín pa dà ní àlàáfíà.+ Àwọn òkè ńlá àtàwọn òkè kéékèèké máa fi igbe ayọ̀ túra ká níwájú yín,+Gbogbo àwọn igi inú igbó sì máa pàtẹ́wọ́.+