Sáàmù 9:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà yóò di ibi ààbò* fún àwọn tí à ń ni lára,+Ibi ààbò ní àkókò wàhálà.+ Sáàmù 142:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà, mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́. Mo sọ pé: “Ìwọ ni ibi ààbò mi,+Gbogbo ohun tí mo ní* lórí ilẹ̀ alààyè.”
5 Jèhófà, mo ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́. Mo sọ pé: “Ìwọ ni ibi ààbò mi,+Gbogbo ohun tí mo ní* lórí ilẹ̀ alààyè.”