Sáàmù 103:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní ti ẹni kíkú, àwọn ọjọ́ rẹ̀ dà bíi ti koríko;+Ó rú jáde bí ìtànná orí pápá.+ 1 Pétérù 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí “gbogbo ẹran ara* dà bíi koríko, gbogbo ògo rẹ̀ sì dà bí ìtànná àwọn ewéko; koríko máa ń gbẹ, òdòdó sì máa ń rẹ̀ dà nù,
24 Torí “gbogbo ẹran ara* dà bíi koríko, gbogbo ògo rẹ̀ sì dà bí ìtànná àwọn ewéko; koríko máa ń gbẹ, òdòdó sì máa ń rẹ̀ dà nù,