Sáàmù 27:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Nítorí yóò fi mí pa mọ́ sí ibi kọ́lọ́fín rẹ̀ ní ọjọ́ àjálù;+Yóò tọ́jú mi pa mọ́ sí ibi ìkọ̀kọ̀ àgọ́ rẹ̀;+Yóò gbé mi sórí àpáta.+ Sáàmù 31:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wàá fi wọ́n pa mọ́ sí ibi ìkọ̀kọ̀ tó wà níwájú rẹ+Kúrò nínú rìkíṣí àwọn èèyàn;Wàá fi wọ́n pa mọ́ sínú àgọ́ rẹKúrò lọ́wọ́ àwọn abanijẹ́.*+ Sáàmù 32:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìwọ ni ibi ìfarapamọ́ mi;Wàá dáàbò bò mí nínú wàhálà.+ Wàá fi igbe ayọ̀ ìgbàlà yí mi ká.+ (Sélà)
5 Nítorí yóò fi mí pa mọ́ sí ibi kọ́lọ́fín rẹ̀ ní ọjọ́ àjálù;+Yóò tọ́jú mi pa mọ́ sí ibi ìkọ̀kọ̀ àgọ́ rẹ̀;+Yóò gbé mi sórí àpáta.+
20 Wàá fi wọ́n pa mọ́ sí ibi ìkọ̀kọ̀ tó wà níwájú rẹ+Kúrò nínú rìkíṣí àwọn èèyàn;Wàá fi wọ́n pa mọ́ sínú àgọ́ rẹKúrò lọ́wọ́ àwọn abanijẹ́.*+