Sáàmù 61:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Màá wà* nínú àgọ́ rẹ títí láé;+Màá fi abẹ́ ìyẹ́ apá rẹ ṣe ibi ààbò.+ (Sélà)