Sáàmù 57:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 57 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi,Nítorí ìwọ ni mo* fi ṣe ibi ààbò,+Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ sì ni mo sá sí títí wàhálà fi kọjá lọ.+
57 Ṣojú rere sí mi, Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi,Nítorí ìwọ ni mo* fi ṣe ibi ààbò,+Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ sì ni mo sá sí títí wàhálà fi kọjá lọ.+